Amodedun Alaga

  • Home
  • Amodedun Alaga

Amodedun Alaga For your wedding engagement,wedding introduction.....
Alaga iduro ati ijoko,mc���
call:0703846

AANU YOO WA IWO ATI IDILE RE RI NI GBOGBO ONA LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY WEEKEND TO YOU ALL ❤️🥰
11/11/2023

AANU YOO WA IWO ATI IDILE RE RI NI GBOGBO ONA LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY WEEKEND TO YOU ALL ❤️🥰

06/11/2023

ISELE IYANU AYO, EYI TO SOORO GBAGBO OLORUN KO FI WA IWO ATI IDILE RE RI LONI, LOSEYI LORUKO JESU KRISTI HAPPY NEW WEEK

01/11/2023

NINU OSU TITUN YI OONI GBA IPE IBANUJE OJIJI LORI AWON OMO RE, IRE RE GBOGBO TO WA NINU OSUYI KO TEELOWO LORUKO JESU KRISTI 🙏

31/10/2023

OSUYI PARI LONI, IDAAMU AYE IWO ATI IDILE RE PARI LONI OTIDI ASEGUN LORUKO JESU KRISTI 🙏

GBOGBO AGBARA TON DI O LOWO TI KO JE KOO NI ASEYORI RERE BOOTIFE ODOPIN LONI LORUKO JESU KRISTI HAPPY NEW WEEK TO YOU AL...
23/10/2023

GBOGBO AGBARA TON DI O LOWO TI KO JE KOO NI ASEYORI RERE BOOTIFE ODOPIN LONI LORUKO JESU KRISTI HAPPY NEW WEEK TO YOU ALL ❤️

21/10/2023

BOTIWU KOOPE LAYE TO MOGBAALADURA FUN O PE OJU RE KO NII RI IBI LORI AWON OMO RE LORUKO JESU KRISTI 🙏

GBOGBO AGBARA TON DENA OGO AYO RE NIGBA GBOGBO KOGBINA SONU NINU AYE RE LORUKO JESU KRISTI 🙏
17/10/2023

GBOGBO AGBARA TON DENA OGO AYO RE NIGBA GBOGBO KOGBINA SONU NINU AYE RE LORUKO JESU KRISTI 🙏

09/10/2023

ODA OHUN RERE GBOGBO KO NII DA IWO ATI IDILE RE LOSEYI ATI NIGBA GBOGBO LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY NEW WEEK

05/10/2023

ILERI IFE AWON OTA KO NII SE LORI IWO ATI IDILE RE LORUKO JESU KRISTI 🙏 LOVE YOU ALL❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

LONI EYI TIISE AYAJO OJO OMINIRA LORI LEDE NIGERIA MO GBAALADURA KI AYE IWO ATI IDILE GBA OMINIRA LATI OKE WA.....KI OHU...
01/10/2023

LONI EYI TIISE AYAJO OJO OMINIRA LORI LEDE NIGERIA MO GBAALADURA KI AYE IWO ATI IDILE GBA OMINIRA LATI OKE WA.....KI OHUN RERE GBOGBO DI IRORUN FUN O LATI ONI LO. LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY INDEPENDENCE DAY AND FIRST SUNDAY IN THE MONTH ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️

AWON OMO RE KO NII SHIRIN LO S**O OLURANLOWO AFOGO ENI SHOFO, AWON OMO RE KO NII KU IKU OJIJI, SUGBON GBOGBO AWON TO SE ...
21/09/2023

AWON OMO RE KO NII SHIRIN LO S**O OLURANLOWO AFOGO ENI SHOFO, AWON OMO RE KO NII KU IKU OJIJI, SUGBON GBOGBO AWON TO SE IKU PA OMO OLOGO YI, IRANDIRAN WON KO NII JEUN OMO LORUKO JESU KRISTI 🙏 ILERI OLUWA IMOLE RIP 🕯️

IWO ABIYAMO SE AMIN DAADA, IMOLE AYE GBOGBO AWON OMO RE KO NII WO LOKUNKUN, IRIN AJO RE LOSEYI YOO YORI SI RERE  LORUKO ...
18/09/2023

IWO ABIYAMO SE AMIN DAADA, IMOLE AYE GBOGBO AWON OMO RE KO NII WO LOKUNKUN, IRIN AJO RE LOSEYI YOO YORI SI RERE LORUKO JESU KRISTI 🙏🙏🙏 HAPPY NEW WEEK TO YOU ALL

13/09/2023

IWO ABIYAMO GBOMI DAADA, OTIMO OJOBI AWON OMO RE, OONI MO SAARE WON LORUKO JESU KRISTI 🙏

MOGBAALADURA FUN O PE OWO AGBARA OLORUN KO GBE GBOGBO AWON OMO RE SOKE DEBI GIGA LAYE LORUKO JESU KRISTI 🙏♥️♥️♥️♥️♥️♥️♥️
08/09/2023

MOGBAALADURA FUN O PE OWO AGBARA OLORUN KO GBE GBOGBO AWON OMO RE SOKE DEBI GIGA LAYE LORUKO JESU KRISTI 🙏♥️♥️♥️♥️♥️♥️♥️

04/09/2023

NINU OSE YI IYANU NLA TI KO SHELERI NINU AYE RE, KOORIIGBA LONI LOSEYI LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY NEW WEEK

01/09/2023

BI A TI SE WONU OSU TUNTUN YI, IRE AYO GBOGBO KOWOLE TO E WA LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY NEW MONTH TO YOU ALL ♥️

26/08/2023

GBOGBO AGBARA IDIWO ATI IDENA NINU AYE IWO ATI AWON OMO RE, KODOKU LONII LORUKO JESU KRISTI 🙏 HAPPY WEEKEND TO YOU ALL 🙋❤️

24/08/2023

GBOGBO OWO AGBARA TI KO JE KOORAYE GBE BOOTIFE KOGBINA SONU LARA RE LONI LORUKO JESU KRISTI 🙏

Address


Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Amodedun Alaga posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Amodedun Alaga:

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Telephone
  • Alerts
  • Contact The Business
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Event Planning Service?

Share